AJASEGUN RELEASES NEW SINGLE “AANU” (CRY FOR MERCY)

0
138

Gospel artiste and Songwriter, Olusegun Emmanuel a.k.a Ajasegun has released yet another inspirational single titled “Aanu” (Cry for Mercy) from his upcoming album “Undefeated by Grace”.

“Aanu” is a song to inspire and encourage everyone going through any sort of tribulations and turbulent times.

“Aanu” is a Cry for Mercy through bringing your supplications, afflictions, tribulations and even thanksgiving to the creator.

“So then it is not of him that willeth, nor of him that runneth, but of God that sheweth mercy” Romans 9:16.

“Aanu” is now available on all digital stores;

Watch Video

DOWNLOAD/STREAM MP3

LYRICS

Intro:

Ninu là là,Ati kókó Ayè

Aanu ni mowa bèrè fun

Aanu ni mowa wa

Kin leje olusegun

Kin le ja ajasegun

Ni Mo fi wa Aanu wa

Baba s’anu mi

Je kin ri anu gba

Je Kin ri anu lo

Chorus;

Baba s’anu mi

K’emi mà se pófó laye mi

Baba gbeja mi

K’emi mà se pofo laye mi

Verse 1;

Bi ina bánjo

B’orun ba’n ran

T’ategun aye fe gbemi lo o(Bi ina bánjo)

Bi mo’n se wolè

Ti mo’n jadè lo

Ti mi o mà leni gbekele o(mà gbekele o)

Iwo ni olorun mimo

Iwo ni olorun funfun

Atobajaye,Eleruniyi

Moyin o l’ogo(2ce)

Emi a gbeke mi le o

Emi a gboju mi le o

Emi a gbokan mi le o(Oga ogo)2ce

Oni ohun yo pami mo

Ninu kpankpe peyèpeyè

Ati ninu ajakale

Ati arun buburu

Odi Jericho mi wo o

Ide mi ti jaa,

mo di ominira

Apanla to sò ile ayero o

Moyin o’logo(2ce)

Emi a gbokan mi le o

Emi a gboju mi le o

Emi a gbeke mi le o(Oga ogo)

(Back 2 chorus)

Call: Atabatubu Eledumare oba

Resp:Baba ni

Call:Apanla to s’ole aye rò

Resp:Iwo ni

Call:Erujeje lèti okun pupa

Resp:S’anu mi

Call:Olorun mimo,olorun funfun

Resp:Gbeja mi

(Baba ni,Baba ni)

Iwo l’olorun Baba mi

(Baba ni…Iwo ni 2ce)

Olorun elà

(Iwo ni 2ce)

(S’anu mi 4x)

Asiwaju ogun a lo

Akeyin la bo

Ota giri lati oju orun

gbomo ti la

Iwo l’arugbo ojo

Ya gbó Ya jò,okunrin ogun

Iwo l’abiamo aboja

Gboro gboro

Muni muni ta o le mu

Moni moni ta o le mo

Iwo la adagba ma te pka

Bi o se dagba to o fopa rin o

Agba,Agba leje o

Agbalagba leje (2ce)

Connect with Ajasegun

Twitter: @Ajasegune

Instagram: Ajasegune

Facebook: Ajasegun Olusegun

YouTube: Olusegun Ajasegun

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here