Music: Iwo Lolorun – Bona Gold

0
313

Gospel music minister, an award winner, Song writer and a recording artist, Bona Gold is out with her long anticipated single titled “Iwo Lolorun”

According to her:
IWO LOLORUN is a song inspired by the Holy Spirit. A song which describes the Greatness of Our God and the mighty work of His Hands.

Download & Share
DOWNLOAD NOW

IWO LOLORUN LYRICS

Iwo Lolorun to GA ju aye lo…
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o le baaa..
Se biwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to…IWO LOLORUN to Lagbara ju gbogbo eniyan lo…
Iwo lolorun ta won Ogun Orun mbooo..
Sebi Iwo lolorun yi o, to Lagbara giga giga, sebi Iwo lolorun yi o te da Kan o le to, Lai laiChr: Iwo lolorun yi GA ju aye lo
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
Se b’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o le baaa
Se b’iwo lolorun yii o, teni Kan Kan o to…Verse1: Awamaridi nii o o, aditu loruko re…
Gbogbo ologbon aye wa Di re o, won o ri Di Agbara re..
Yeeee, Okun ati Osa nhooo, won o ridi Agbara ra re.
Eja Inu ibi, sa pe juwe ise owo re
Bi afefe ti n fe, O sa pejuwe ise re..
Eniyan atewe be, sa pejuwe ise owo re….
Iwo nii o(back to Chorus)
Sax medley…… Modulation
(back 2 chorus)Iwo lolorun to GA ju aye lo
“IWO nii ooo”
” Baba miii”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“seb’iwo loga ju eniyan lo Alagbara giga”
Se bi’wo lolorun yi o
“IWO ni, Iwo ni o”
Teni Kan Kan o le baaa
“There’s no one that can compare with your name Lord”
Sebi Iwo lolorun yi o o “Arugbo Ojo baba mii
Teni Kan Kan o to…
” You are great ”
(chorus)Iwo lolorun to GA ju aye lo
” there’s no one that can share your glory ”
” You are the king of kings”
“You are the Lord of Lord’s”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“the ancient of days, the rock of ages”
“you are the mighty man in battle ”
Sebi Iwo lolorun yi o te ni Kan tan o le baaa
“I bless your name Lord”
“I worship you Lord, I refrerence your name”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o to..
“there’s none like you, there’s none like you…
” We say Holy are you Lord”
Iwo lolorun to GA ju aye lo
” Lord you are Holy, you are the Oba Arugbo Ojo”
“Oba mi adagba ma te PA, Oba mi adagba ma lo gilaaasi”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“” Eru jeje to mi gbo kiji kiji”
“I bless your name Jesus”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o le baaa
“I worship you Lord” I bless you Lord”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o to…Call: Eleti gba ro ye Eda o
Eleti Kara bi ajere
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Call: Oba mi okan soso ajanaku o, to mi gbo kiji kiji yeee
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Call : Oba mi to loyun Ara re, to gbebi Ara re, to tun wa so ra re loruko, laye lorun ko so’ba bi re o..
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Till fades….
.

Social media details:  

Facebook: Bona Gold

Instagram: bonagold1

Youtube: Bona Gold–

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here